Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 50:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n dé ibi ìpakà Atadi, níwájú Jọdani, wọ́n pohùnréré ẹkún, Josẹfu sì ṣọ̀fọ̀ baba rẹ̀ fún ọjọ́ meje.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 50

Wo Jẹnẹsisi 50:10 ni o tọ