Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 37:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó rọ́ àlá náà fún baba rẹ̀ ati àwọn arakunrin rẹ̀. Baba rẹ̀ bá a wí, ó ní, “Irú àlá rándanràndan wo ni ò ń lá wọnyi? Ṣé èmi, ati ìyá rẹ, ati àwọn arakunrin rẹ yóo wá foríbalẹ̀ fún ọ ni?”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 37

Wo Jẹnẹsisi 37:10 ni o tọ