Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 37:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún lá àlá mìíràn, ó sì tún rọ́ ọ fún àwọn arakunrin rẹ̀, ó ní, “Ẹ gbọ́, mo mà tún lá àlá mìíràn! Mo rí oòrùn, ati òṣùpá, ati àwọn ìràwọ̀ mọkanla ní ojú àlá, gbogbo wọn foríbalẹ̀ fún mi.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 37

Wo Jẹnẹsisi 37:9 ni o tọ