Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 37:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn arakunrin rẹ̀ bá bẹ̀rẹ̀ sí ṣe ìlara rẹ̀, ṣugbọn baba rẹ̀ kò gbàgbé ọ̀rọ̀ náà, ó ń rò ó ní ọkàn rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 37

Wo Jẹnẹsisi 37:11 ni o tọ