Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 24:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà bá wọlé, Labani sì tú gàárì àwọn ràkúnmí rẹ̀, ó fi koríko ati oúnjẹ fún wọn. Ó fún un ní omi láti fi ṣan ẹsẹ̀ rẹ̀ ati ẹsẹ̀ àwọn ọkunrin tí wọ́n bá a wá.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24

Wo Jẹnẹsisi 24:32 ni o tọ