Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 24:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé oúnjẹ wá fún un pé kí ó jẹ, ṣugbọn ó wí pé, “N kò ní jẹun títí n óo fi jíṣẹ́ tí wọ́n rán mi.” Labani dáhùn, ó ní, “À ń gbọ́.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24

Wo Jẹnẹsisi 24:33 ni o tọ