Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 15:18-21 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Ní ọjọ́ náà ni OLUWA bá a dá majẹmu, ó sọ pé, “Àwọn ọmọ rẹ ni n óo fi ilẹ̀ yìí fún, láti odò Ijipti títí dé odò ńlá nì, àní odò Yufurate,

19. ilẹ̀ àwọn ará Keni, ti àwọn ará Kenisi, ti àwọn ará Kadimoni,

20. ti àwọn ará Hiti, ti àwọn ará Perisi, ti àwọn ará Refaimu,

21. ti àwọn ará Amori, ti àwọn ará Kenaani, ti àwọn ará Girigaṣi ati ti àwọn ará Jebusi.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 15