Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 15:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà ni OLUWA bá a dá majẹmu, ó sọ pé, “Àwọn ọmọ rẹ ni n óo fi ilẹ̀ yìí fún, láti odò Ijipti títí dé odò ńlá nì, àní odò Yufurate,

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 15

Wo Jẹnẹsisi 15:18 ni o tọ