Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 15:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí oòrùn wọ̀, tí ilẹ̀ sì ṣú, kòkò iná tí ó ń rú èéfín ati ìtùfù tí ń jò lálá kan kọjá láàrin àwọn ẹran tí Abramu tò sílẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 15

Wo Jẹnẹsisi 15:17 ni o tọ