Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 8:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo fi tọkàntọkàn pinnu láti wá ọgbọ́n ati láti wo iṣẹ́ tí wọn ń ṣe ní ayé, bí eniyan kì í tíí fi ojú ba oorun tọ̀sán-tòru,

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 8

Wo Ìwé Oníwàásù 8:16 ni o tọ