Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 8:17 BIBELI MIMỌ (BM)

mo wá rí gbogbo iṣẹ́ Ọlọrun pé, kò sí ẹni tí ó lè rí ìdí iṣẹ́ tí ó ń ṣe láyé. Kò sí bí eniyan ti lè ṣe làálàá tó, kò lè rí ìdí rẹ̀. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n ń sọ pé àwọn mọ iṣẹ́ OLUWA, sibẹsibẹ wọn kò lè rí ìdí rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 8

Wo Ìwé Oníwàásù 8:17 ni o tọ