Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìmọ̀ràn mi ni pé, kí eniyan máa gbádùn, nítorí kò sí ire kan tí ọmọ eniyan tún ń ṣe láyé ju pé kí ó jẹ, kí ó mu, kí ó sì gbádùn lọ; nítorí èyí ni yóo máa bá a lọ ní gbogbo ọjọ́ tí Ọlọrun fún un láyé.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 8

Wo Ìwé Oníwàásù 8:15 ni o tọ