Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 8:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun asán kan tún wà tí ń ṣẹlẹ̀ nílé ayé yìí, a rí àwọn olódodo tí wọn ń jẹ ìyà àwọn eniyan burúkú, tí eniyan burúkú sì ń gba èrè olódodo, asán ni èyí pẹlu.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 8

Wo Ìwé Oníwàásù 8:14 ni o tọ