Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 7:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ó yá tí n óo bínú si yín, tí inú mi óo ru si yín gidi. N óo da yín lẹ́jọ́ gẹ́gẹ́ bí ìwà yín, n óo sì jẹ yín níyà nítorí gbogbo ìwà ìríra yín.

Ka pipe ipin Isikiẹli 7

Wo Isikiẹli 7:8 ni o tọ