Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 7:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wò ó! Ó ti dé. Ìparun ti dé ba yín, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé ilẹ̀ yìí. Àkókò tó, ọjọ́ ti súnmọ́lé, ọjọ́ ìdàrúdàpọ̀, tí kì í ṣe ọjọ́ ariwo ayọ̀ lórí àwọn òkè.

Ka pipe ipin Isikiẹli 7

Wo Isikiẹli 7:7 ni o tọ