Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 7:9 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò ní fojú fo ọ̀rọ̀ yín, n kò ní ṣàánú yín. N óo jẹ yín níyà gẹ́gẹ́ bí ìwà yín, níwọ̀n ìgbà tí ohun ìríra ṣì wà láàrin yín. Ẹ óo wá mọ̀ nígbà náà pé èmi OLUWA, ni mò ń jẹ yín níyà.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 7

Wo Isikiẹli 7:9 ni o tọ