Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 48:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Apá ìhà gúsù tí ó jẹ́ ẹgbaa meji ó lé ẹẹdẹgbẹta (4,500) igbọnwọ (mita 2,250), yóo ní ẹnu ọ̀nà mẹta. Orúkọ wọn yóo máa jẹ́ ẹnubodè Simeoni, ẹnubodè Isakari ati ẹnubodè Sebuluni.

Ka pipe ipin Isikiẹli 48

Wo Isikiẹli 48:33 ni o tọ