Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 48:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Apá ìlà oòrùn tí ó jẹ́ ẹgbaa meji ó lé ẹẹdẹgbẹta (4,500) igbọnwọ (mita 2,250), yóo ní ẹnu ọ̀nà mẹta. Orúkọ wọn yóo máa jẹ́ ẹnubodè Josẹfu, ẹnubodè Bẹnjamini ati ẹnubodè Dani.

Ka pipe ipin Isikiẹli 48

Wo Isikiẹli 48:32 ni o tọ