Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 48:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ wọn yóo máa jẹ́ ẹnubodè Reubẹni, ẹnubodè Juda ati ẹnubodè Lefi. Orúkọ àwọn ẹ̀yà Israẹli ni a fi sọ àwọn ẹnu ọ̀nà ìlú.

Ka pipe ipin Isikiẹli 48

Wo Isikiẹli 48:31 ni o tọ