Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 42:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà ó mú mi jáde, ó mú mi wọ inú gbọ̀ngàn ti inú lápá ìhà àríwá, ó sì mú mi wọ inú àwọn yàrá tí ó wà níwájú àgbàlá Tẹmpili, ati níwájú ilé tí ó wà ní ìhà àríwá.

Ka pipe ipin Isikiẹli 42

Wo Isikiẹli 42:1 ni o tọ