Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 42:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Òòró ilé tí ó wà ní ìhà àríwá náà jẹ́ ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 50), ìbú rẹ̀ sì jẹ́ aadọta igbọnwọ (mita 25).

Ka pipe ipin Isikiẹli 42

Wo Isikiẹli 42:2 ni o tọ