Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 32:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò sin wọ́n bí àwọn alágbára tí wọ́n wà ní àtijọ́ tí wọ́n sin sí ibojì pẹlu ohun ìjà ogun wọn lára wọn: àwọn tí a gbé orí wọn lé idà wọn, wọ́n sì fi asà wọn bo egungun wọn mọ́lẹ̀; nítorí àwọn alágbára wọnyi dẹ́rù bani nígbà tí wọ́n wà láàyè.

Ka pipe ipin Isikiẹli 32

Wo Isikiẹli 32:27 ni o tọ