Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 32:26 BIBELI MIMỌ (BM)

“Meṣeki ati Tubali wà níbẹ̀ pẹlu ogunlọ́gọ̀ àwọn eniyan wọn. Ibojì wọn yí ibojì rẹ̀ ká, gbogbo wọn ni wọ́n kú lójú ogun ní aláìkọlà. Nítorí wọ́n ń dẹ́rù bani nígbà tí wọ́n wà láàyè.

Ka pipe ipin Isikiẹli 32

Wo Isikiẹli 32:26 ni o tọ