Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 21:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọfà ìbò Jerusalẹmu yóo bọ́ sí ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀. Yóo kígbe, àwọn eniyan náà yóo sì kígbe sókè. Wọn óo gbé igi tí wọ́n fi ń fọ́ ìlẹ̀kùn ti ìlẹ̀kùn bodè rẹ̀, wọn yóo mọ òkítì sí ara odi rẹ̀, wọn yóo sì mọ ilé ìṣọ́ tì í.

Ka pipe ipin Isikiẹli 21

Wo Isikiẹli 21:22 ni o tọ