Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 21:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ọba Babiloni ti dúró sí oríta, ní ibi tí ọ̀nà ti pínyà; ó dúró láti ṣe àyẹ̀wò. Ó mi ọfà, ó bá oriṣa sọ̀rọ̀, ó sì woṣẹ́ lára ẹ̀dọ̀ ẹran.

Ka pipe ipin Isikiẹli 21

Wo Isikiẹli 21:21 ni o tọ