Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 21:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ohun tí ó ń ṣe yóo dàbí ẹni tí ń dífá irọ́ lójú àwọn ará ìlú, nítorí pé majẹmu tí wọ́n ti dá yóo ti kì wọ́n láyà; ṣugbọn ọba Babiloni yóo mú wọn ranti ẹ̀ṣẹ̀ wọn, yóo ṣẹgun wọn yóo sì kó wọn lọ.

Ka pipe ipin Isikiẹli 21

Wo Isikiẹli 21:23 ni o tọ