Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 16:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé o kò ranti ìgbà èwe rẹ, ṣugbọn o mú mi bínú nítorí nǹkan wọnyi. Nítorí náà n óo da èrè iṣẹ́ ọwọ́ rẹ lé ọ lórí. Ṣé o kò tún ti fi ìwà ainitiju kún ìwà ìríra rẹ?” OLUWA Ọlọrun ni ó sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 16

Wo Isikiẹli 16:43 ni o tọ