Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 16:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni n óo ṣe tẹ́ ibinu mi lọ́rùn lára rẹ, n kò sì ní jowú nítorí rẹ mọ́. Ara mi yóo rọlẹ̀, inú kò sì ní bí mi mọ́.

Ka pipe ipin Isikiẹli 16

Wo Isikiẹli 16:42 ni o tọ