Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 16:44 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní: “Gbogbo eniyan ni yóo máa pa òwe yìí mọ́ ìwọ Jerusalẹmu pé: ‘Òwú ìyá gbọ̀n ni ọmọ óo ran, bí ìyá bá ti rí ni ọmọ rẹ̀ obinrin yóo rí.’

Ka pipe ipin Isikiẹli 16

Wo Isikiẹli 16:44 ni o tọ