Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 2:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo lọ sibẹ ní alẹ́, ní òwúrọ̀ yóo pada wá sí ilé keji tí àwọn ayaba ń lò, tí ó wà ní abẹ́ ìtọ́jú Ṣaaṣigasi, ìwẹ̀fà tí ó ń tọ́jú àwọn obinrin ọba. Kò tún ní pada lọ rí ọba mọ́, àfi bí inú ọba bá dùn sí i tí ó sì ranṣẹ pè é.

Ka pipe ipin Ẹsita 2

Wo Ẹsita 2:14 ni o tọ