Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 2:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó tó àkókò fún Ẹsita, ọmọ Abihaili ẹ̀gbọ́n Modekai, láti lọ rí ọba, Ẹsita kò bèèrè nǹkankan ju ohun tí Hegai, ìwẹ̀fà ọba tí ń tọ́jú àwọn ayaba, sọ fún un pé kí ó mú lọ. Ẹsita rí ojurere lọ́dọ̀ àwọn tí wọ́n rí i.

Ka pipe ipin Ẹsita 2

Wo Ẹsita 2:15 ni o tọ