Ẹ wo àwọn ọdọmọkunrin Sioni,àwọn ọmọ tí wọn níye lórí bí ojúlówó wúrà,tí a wá ń ṣe bí ìkòkò amọ̀;àní, bí ìkòkò amọ̀ lásánlàsàn.