Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremaya 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Wo bí wúrà ti dọ̀tí,tí ojúlówó wúrà sì yipada;tí àwọn òkúta Tẹmpili mímọ́ sì fọ́nká ní gbogbo ìkóríta.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 4

Wo Ẹkún Jeremaya 4:1 ni o tọ