Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 38:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ti àwọn ọ̀pá náà bọ àwọn òrùka tí wọ́n wà ní ẹ̀gbẹ́ kinni keji pẹpẹ náà láti máa fi gbé e; pákó ni ó fi ṣe àwọn ọ̀pá náà, wọ́n sì ní ihò ninu.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:7 ni o tọ