Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 38:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mu dígí onídẹ, tí àwọn obinrin tí ń ṣiṣẹ́ ìsìn lẹ́nu ọ̀nà àgọ́ ń lò, ó fi ṣe agbada idẹ kan, ati ìtẹ́lẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:8 ni o tọ