Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 30:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí ẹnìkọ̀ọ̀kan tí o bá kà yóo san ni: ìdajì ṣekeli, tí a fi ìwọ̀n ilé OLUWA wọ̀n, (tí ó jẹ́ ogún ìwọ̀n gera fún ìwọ̀n ṣekeli kan), ìdajì ṣekeli náà yóo sì jẹ́ ti OLUWA.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 30

Wo Ẹkisodu 30:13 ni o tọ