Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun tún fi kún un fún Mose pé kí ó sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé OLUWA Ọlọrun àwọn baba wọn, Ọlọrun Abrahamu, Ọlọrun Isaaki, ati Ọlọrun Jakọbu, ni ó rán òun sí wọn. Ó ní orúkọ òun nìyí títí ayérayé, orúkọ yìí ni wọn óo sì máa fi ranti òun láti ìrandíran.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 3

Wo Ẹkisodu 3:15 ni o tọ