Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 3:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Lọ kó gbogbo àwọn àgbààgbà Israẹli jọ, kí o sì sọ fún wọn pé, èmi OLUWA, Ọlọrun àwọn baba yín, Ọlọrun Abrahamu, Ọlọrun Isaaki ati Ọlọrun Jakọbu, ni ó farahàn ọ́, ati pé, mo ti ń ṣàkíyèsí wọn, mo ti rí ohun tí àwọn ará Ijipti ti ṣe sí wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 3

Wo Ẹkisodu 3:16 ni o tọ