Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun dá Mose lóhùn pé, “ÈMI NI ẸNI TÍ MO JẸ́. Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, ‘ÈMI NI ni ó rán mi sí yín.’ ”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 3

Wo Ẹkisodu 3:14 ni o tọ