Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 21:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ó bá jẹ́ mààlúù náà ti kan eniyan tẹ́lẹ̀, tí wọ́n sì ti kìlọ̀ fún ẹni tí ó ni ín, tí kò sì so ó mọ́lẹ̀, bí ó bá pa eniyan, kí wọn sọ mààlúù náà ní òkúta pa, kí wọn sì pa ẹni tí ó ni ín pẹlu.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21

Wo Ẹkisodu 21:29 ni o tọ