Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 21:28 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí mààlúù bá kan eniyan pa, kí wọ́n sọ mààlúù náà ní òkúta pa. Ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ jẹ ẹran rẹ̀; ṣugbọn kí ẹnikẹ́ni má ṣe jẹ ẹni tí ó ni mààlúù náà níyà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21

Wo Ẹkisodu 21:28 ni o tọ