Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ya gbogbo àwọn àkọ́bí sí mímọ́ fún mi, ohunkohun tí ó bá ti jẹ́ àkọ́bí láàrin àwọn eniyan Israẹli, kì báà ṣe ti eniyan, tabi ti ẹranko, tèmi ni wọ́n.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 13

Wo Ẹkisodu 13:2 ni o tọ