Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, kí ẹ mọ̀ lónìí pé, OLUWA Ọlọrun yín ni ó ń lọ níwájú yín, bíi iná ajónirun. Yóo pa wọ́n run, yóo sì tẹ orí wọn ba fun yín, nítorí náà, kíá ni ẹ óo lé wọn jáde, tí ẹ óo sì pa wọ́n run, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti ṣe ìlérí fun yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 9

Wo Diutaronomi 9:3 ni o tọ