Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 9:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí OLUWA Ọlọrun yín bá lé wọn jáde fun yín, ẹ má ṣe wí ninu ọkàn yín pé, ‘Nítorí òdodo wa ni OLUWA ṣe mú wa wá láti gba ilẹ̀ yìí, bẹ́ẹ̀ sì ni nítorí ìwà burúkú àwọn orílẹ̀-èdè wọnyi ni OLUWA ṣe lé wọn jáde fún wa.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 9

Wo Diutaronomi 9:4 ni o tọ