Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 9:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan náà pọ̀, wọ́n ṣígbọnlẹ̀. Àwọn òmìrán tíí ṣe ìran Anakimu ni wọ́n. Àwọn tí ẹ ti mọ̀, tí ẹ sì ti ń gbọ́ nípa wọn pé, ‘Ta ni ó lè dúró níwájú àwọn ìran Anaki?’

Ka pipe ipin Diutaronomi 9

Wo Diutaronomi 9:2 ni o tọ