Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 9:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ óo la odò Jọdani kọjá sí òdìkejì lónìí, ẹ óo sì gba ilẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n pọ̀ jù yín lọ, tí wọ́n sì lágbára jù yín lọ. Àwọn ìlú wọn tóbi, tí odi tí wọ́n mọ yí wọn ká sì ga kan ojú ọ̀run.

Ka pipe ipin Diutaronomi 9

Wo Diutaronomi 9:1 ni o tọ