Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo mú gbogbo àrùn kúrò lọ́dọ̀ yín, kò sì ní fi ẹyọ kan ninu gbogbo àwọn àrùn burúkú ilẹ̀ Ijipti, tí ẹ mọ̀, ba yín jà. Ṣugbọn yóo dà wọ́n bo àwọn tí wọ́n kórìíra yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 7

Wo Diutaronomi 7:15 ni o tọ