Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 7:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Píparun ni ẹ óo pa gbogbo àwọn eniyan tí OLUWA Ọlọrun yín yóo fi lé yín lọ́wọ́ run, ẹ kò gbọdọ̀ ṣàánú wọn, bẹ́ẹ̀ sì ni ẹ kò gbọdọ̀ bọ àwọn oriṣa wọn, nítorí ohun ìkọsẹ̀ ni wọn yóo jẹ́ fun yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 7

Wo Diutaronomi 7:16 ni o tọ