Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 33:9 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn tí wọ́n sọ pé àwọn kò ka òbí àwọn sí, ju ìwọ OLUWA lọ;wọ́n kọ àwọn arakunrin wọn sílẹ̀,wọ́n sì ṣá àwọn ọmọ wọn tì.Nítorí pé wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ,wọ́n sì ń pa majẹmu rẹ mọ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 33

Wo Diutaronomi 33:9 ni o tọ