Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 33:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo kọ́ ilé Jakọbu ní ìlànà rẹ,wọn óo sì kọ́ àwọn ọmọ Israẹli ní òfin rẹ.Àwọn ni wọn óo máa sun turari níbi ẹbọ rẹ,wọn óo sì máa rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ rẹ.

Ka pipe ipin Diutaronomi 33

Wo Diutaronomi 33:10 ni o tọ